Obinrin je eniti won nfi oju re rare, eniyepere nigba aimokan titi ti esin Islam fi de, ti o gbe aponle ti ko ni afiwe fun-un, ti o si laa kuro nibi abosi aimokan, ti o si fi awon etoo re rinle fun-un, o si se obinrin ni dogba pelu okunrin nibi opolopo awon oranyan esin, ati nibi esan ati ijiya, obinrin ko ri igbeaponle funni ati iyi gegebii o se ri ninu awon ofin esin Islam.

Obinrin je eniti won nfi oju re rare, eniyepere nigba aimokan titi ti esin Islam fi de, ti o gbe aponle ti ko ni afiwe fun-un, ti o si laa kuro nibi abosi aimokan, ti o si fi awon etoo re rinle fun-un, o si se obinrin ni dogba pelu okunrin nibi opolo ...

Ijee omoiya je idera kan ti o tobi lati odo Olohun , ati ajulo ti o nsan lati odo Olohun ti o gbooro lori awon muumini ododo, ijee omoiya je nkan mimun ti o mo ti Olohun maa nfun awon muumini eniire mun, dajudaju, Islam tii seni lojukokoro lori si soo ibasepo musulumi ati omoiya re di ninipon, O si see awon alaamori kan lofin fun-un ti yio soo di eleyi ti o ni agbara gegebii; ifon salamo ka, ati ilo bee alaare wo ati bee bee lo ninu awon etoo musulumi kan lori omoiya re.

Ijee omoiya je idera kan ti o tobi lati odo Olohun , ati ajulo ti o nsan lati odo Olohun ti o gbooro lori awon muumini ododo, ijee omoiya je nkan mimun ti o mo ti Olohun maa nfun awon muumini eniire mun, dajudaju, Islam tii seni lojukokoro lori si so ...

Idaa okun ibi po je alaamori kan ti Olohun fi maa ngbooro arisiki, O si tun je okunfa emigigun, Olohun si maa nfi se ibukun dukia eniyan, idaibipo je apere pipee igbagbo ati didaa Islam eniyan, ni ida miran, ijakun ebi je okunfa ibidandan Olohun ati ijiya re, ati egbee ati iya, ti yio maa pa alubarika re, ti yio  si maa jogun  ota sise ati ikorira eni.

Idaa okun ibi po je alaamori kan ti Olohun fi maa ngbooro arisiki, O si tun je okunfa emigigun, Olohun si maa nfi se ibukun dukia eniyan, idaibipo je apere pipee igbagbo ati didaa Islam eniyan, ni ida miran, ijakun ebi je okunfa ibidandan Olohun ati ...

Odun itunu aawe je okan ninu odun meji ti Olohun Oba Alekeola se ni eto fun awa musulumi lati fi maa dupe oore re ti a o le ka tan lewa lori lati ara iroro igba aawe osu nla(osu Ramadan) ati sise awon oniranran ijosin fun-un ninu re ni irorun.

Odun itunu aawe je okan ninu odun meji ti Olohun Oba Alekeola se ni eto fun awa musulumi lati fi maa dupe oore re ti a o le ka tan lewa lori lati ara iroro igba aawe osu nla(osu Ramadan) ati sise awon oniranran ijosin fun-un ninu re ni irorun.

Dajudaju, ninu ohun ti o ga julo ti Olohun se ni oranyan ninu dukia ni zakah yiyo je, oun si ni eekete awon origun Islam, ati olukoworin irun ninu asokale Alukurani, niti paapaa, Olohun ti see ni ofin fun ogbon ti o dogongo, beeni, ko se ni ofin lati gba ninu dukia awon eru lasan, bikosepe, O je ohun isoo dukia won dii mimo, O si je iranlowo fun awon alaini won, ti yio maa je okunfa alekun ife laarin won, niti ifowosowopo ati amojuto ti ibasepo laarin mutunmuwa ni  awujo.

Dajudaju, ninu ohun ti o ga julo ti Olohun se ni oranyan ninu dukia ni zakah yiyo je, oun si ni eekete awon origun Islam, ati olukoworin irun ninu asokale Alukurani, niti paapaa, Olohun ti see ni ofin fun ogbon ti o dogongo, beeni, ko se ni ofin lati ...