Iranti Olohun(Asikiri) fun okan da gegebi omi fun eja, bawo ni eja se maa semi laisi omi? dajusaka, esin to duro deede ti gbewalongbe wipe ki musulumi maa sopo maa Oluwa re ki okan re le ba je alaaye ati lati tun maa se afomo ati imototo emi, ati lati maa

Iranti Olohun(Asikiri) fun okan da gegebi omi fun eja, bawo ni eja se maa semi laisi omi? dajusaka, esin to duro deede ti gbewalongbe wipe ki musulumi maa sopo maa Oluwa re ki okan re le ba je alaaye ati lati tun maa se afomo ati imototo emi, ati lat ...

Ninu ohun ti o ye ki musulumi gbe ola fun ni orun ti a mo si Alikiyamo je sugbon opolopo ninu awon omo eda eniyan ni o ko airoju pelu isemi aye nikan eleyii ti yio tan laisi tabisugbon, ti o ba je bee E je ki a gbe ola ati ajulo fun orun wa aaye ti a o maa wa gbere.

Ninu ohun ti o ye ki musulumi gbe ola fun ni orun ti a mo si Alikiyamo je sugbon opolopo ninu awon omo eda eniyan ni o ko airoju pelu isemi aye nikan eleyii ti yio tan laisi tabisugbon, ti o ba je bee E je ki a gbe ola ati ajulo fun orun wa aaye ti a ...

Obinrin je eniti won nfi oju re rare, eniyepere nigba aimokan titi ti esin Islam fi de, ti o gbe aponle ti ko ni afiwe fun-un, ti o si laa kuro nibi abosi aimokan, ti o si fi awon etoo re rinle fun-un, o si se obinrin ni dogba pelu okunrin nibi opolopo awon oranyan esin, ati nibi esan ati ijiya, obinrin ko ri igbeaponle funni ati iyi gegebii o se ri ninu awon ofin esin Islam.

Obinrin je eniti won nfi oju re rare, eniyepere nigba aimokan titi ti esin Islam fi de, ti o gbe aponle ti ko ni afiwe fun-un, ti o si laa kuro nibi abosi aimokan, ti o si fi awon etoo re rinle fun-un, o si se obinrin ni dogba pelu okunrin nibi opolo ...

Alijanna ogba idera je oja ti o won, eleyi ti o se wipe awon osise nsise nitori re, nibe ni awon oju ti o ntanmole, ti o nrerin ti o ndunnu wa, nibe ni ewa ti o foju han  ati awon omoge eleyinjuege wa. Ni ida miran, ina je iya gbere, nibe ni awon omi igbona, iya eletaelero, ti  oniyepere wa. Enikan ko ni mo alijanna ayafi ki o daamu ati waa, enikan ko si ni mo ina ayafi ki o daamu atisa fun.

Alijanna ogba idera je oja ti o won, eleyi ti o se wipe awon osise nsise nitori re, nibe ni awon oju ti o ntanmole, ti o nrerin ti o ndunnu wa, nibe ni ewa ti o foju han ati awon omoge eleyinjuege wa. Ni ida miran, ina je iya gbere, nibe ni awon omi ...

Imo je imole ati onaamo, aimokan si je okunkun ati anu, imo pelu igbagbo je agbega laye ati lorun, lilo imo ni eso re, ohun si ni ipinle imo ati erongba lori re, o je oranyan lori awon akeeko imo ki won maa sise too ohun ti won mo, ti won ba se bee, imo naa yio je abamo ati adanu fun won, onimimo ti kii ba lo imo re da gegebii abela ti o ntan imonle fun awon eniyan ti o si yo ara re.

Imo je imole ati onaamo, aimokan si je okunkun ati anu, imo pelu igbagbo je agbega laye ati lorun, lilo imo ni eso re, ohun si ni ipinle imo ati erongba lori re, o je oranyan lori awon akeeko imo ki won maa sise too ohun ti won mo, ti won ba se bee, ...